Aare Muhamadu Buhari loni ti fi owo si iwe abadofin ti yo fun awon odo orilede Nigeria ni anfani lati le du ipo ati gbegba oselu ni orilede Nigeria.
Aare Buhari ninu atejade to se ni ojo ayeye ijoba alagbada ti fi idi re mule wipe lai pe , lai jina, ohun yo fowo si abadofin na.
Comments
Post a Comment