Awon osise ajo EFCC ti gbe Gomina ipinle Kaduna nigbakanri Ramalan Yero fun esun jibiti. Oga agba ajo EFCC to wa ni ipinle na Kamaludeen Gebi nigba ton ba awon akoroyin soro so wipe awon ti setan lati gbe Gomina nigbakanri na ati awon meta miran ti won fura si wipe won lowo ninu esun na lo si ile ejo kan to wa ni ilu Abuja ni ose ton bo.
Comments
Post a Comment