Awon omo egbe agbaboolu Super Eagles se ipade pelu Aare Buhari ni Abuja loni

Aare Buhari loni gba awon omo egbe agbaboolu Super Eagles ni alejo ni ile ijoba to wa ni ilu Abuja loni. Nibi ipade na, o ki won ku ise, o si ro won ki won gbiyanju lati gbe orilede Nigeria de ipile to joju nibi idije World Cup ton bo ni orilede Russia.

Comments