Dele Momodu baba oni ikun nla, Davido ni ma fi ejo e sun - Lere Olayinka

Ija be sile loni laarin Dele Momodu ati ikan ninu awon osise Gomina ipinle Ekiti, ogbeni Lere Olayinka. Ogbeni Lere Olayinka lo fi enu abuku kan ogbeni Dele Momodu fun iwa atenuje ton wu, latari bo tin ba Fayemi polongo fun idibo Gomina ton bo lona ni ipinle Ekiti.
 Pari-pari re ni Ogbeni Lere Olayinka kilo fun Dele Momodu wipe ti ko ba sora re, ohun yo fi ejo re sun Davido lati ko leko.


''See how @DeleMomodu is messing himself up on Instagram. Just the way this buffon called Dele Momodu campaigned for Calamity Buhari, he is also campaigning for Failure Fayemi. Olofo somebody''
Dele Momodu did not find Lere's comment funny and so he fired at him in his comment section. They had an exchange of words with Lere threatening to report Momodu to singer Davido.
See their exchanges below

Comments