Iko egbe agbaboolu Real Madrid ti gbo omi ewuro si oju egbe agbaboolu Liverpool nigbati won na won ni omi ayo meta si ikan (3-1)





Iko egbe agbaboolu Real Madrid na awon akegbe won RealMadrid ninu idije to waye laarin won lati fi gba ife eye UEFA CHAMPIONS LEAGUE. Ogbeni Karim Benzema lo koko gba omi ayo kan wole fun Real Madrid, Dejan Lovren gba ikan wole fun Liver Pool.
 Ogbeni Gareth Bale si fi omi ayo meji le fun egbe agbaboolu Real Madrid.

Comments