Ile ejo ti fi Gomina ipinle Taraba nigbakanri Jolly Nyame si ewon odun merila fun esun jibiti

Ile ejo to wa ni ilu Abuja labe igbejo adajo agba Justice Adebunkola Banjoko ti fi Gomina ipinle Taraba nigbakanri Jolly Nyame si ewon odun merinla fun esu jibiti nigba to je Gomina ipinle na.
 Adajo Banjoko fi idi re mule wipe Gomina na ti ko owo toto billion kan ati abo  1.5billion je nigba ti je Gomina ipinle na ni odun 1999 si 2007.

Comments