O kere tan awon eyan merin ti so emi won nu ninu ijamba oko kan to sele ni opopona Benin si Auchi +18







Ijamba oko kan to sele ni agbegebe Jattu ni opopona Benin si Auchi ni ijoba ipinle Auchi ni awon merin o kere tan ti so emi won nu.
Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won se, won so wipe oko ajagbe kan lo gba oko ayokele Golf kan, ti o si lo fi ori so awon oko ayokele miran ton bo lona. Awon osise ajo FRSC ton soju ipinle na, ti wa gbe oku awon to so emi won nu lo si ite igbokusi to wa ni ipinle na.

Comments