O ma se o! Oga agba ile ise iwe iroyin Punch;Wale Aboderin ti ku

Ibanuje nla lo je nigbati iroyin iku oga agba ile ise iwe iroyin Punch Gbadebowale Wayne Aboderin to wa leti. Iwadi fi ye wa wipe nkan bi ago mefa aro ni ogbon ojo ninu osu karun odun yi ni akoni na fi aye sile lo.
Omo ogota odun ni ologbe na ki olojo to de. Adura wa ni wipe ki Olorun fi orun ke ologbe na. Amin.

Comments