Awon eyan mejo o kere tan lo ti jona ninu ijamba oko kan to sele ni opopona Epinmi-Isua Akoko ni ijoba ipinle Akoko South-East ni ipinle Ondo. Gege bi atejade ti eni ti oro na se oju re so, o so wipe oko akero kan lo gba oko ayokele Range Rover kan ti awon oko mejeji na si gbina.
Igba ti awon akoroyin wa ba awon osise ajo FRSC soro, won so wipe ibanuje nla lo je fun awon nigba ti awon ri oku awon eyan to ti jona. O so siwaju si wipe awon eyan na to ogun, wipe awon si ti gbe oku won lo si ite igboku si.

Comments
Post a Comment