Senator Dino Melaye ti kuro ninu egbe oloselu APC bo si egbe oloselu PDP
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Senator Dino Melaye ni aro kutu-kutu oni ti se atejade kan loni lati fi han wipe ohun ti setan lati kuro ninu egbe oloselu APC bo si egbe oloselu PDP. O se eleyi latari ija ati awo to wa laarin ohun ati awon omo egbe oloselu APC.
Comments
Post a Comment