Kayefi nla lo je fun gbogbo awon ololufe boolu alafesegba ati awon ololufe egbe agbaboolu Real Madrid nigba ti oluko agba egbe agbaboolu na Zinedine Zidane se atejade wipe ohun ti setan lati feyinti ki ohun si kowe fi ise sile gege bi oluko agba egbe agbaboolu na.
Eyi waye leyin ojo melo kan ti egbe agbaboolu na gba ife eye Champions League fun igba meta lera-lera.
Eyi waye leyin ojo melo kan ti egbe agbaboolu na gba ife eye Champions League fun igba meta lera-lera.
Comments
Post a Comment