Aare Buhari ti se atejade kan lati fi kedun pelu awon to so emi wonnu ninu ijamaba oko ajepo to sele ni ori oke afara Otedola ni oju opopona marose Eko si Ibadan ni ana.
Atejade to se ni yi ni ede geesi;
''President @MBuhari sympathizes with the Government and people of Lagos State, and the victims of the tanker fire incident at the #OtedolaBridge. May the souls of the dead rest in peace, and may God comfort all those who lost loved ones. The entire country mourns with you''.
Comments
Post a Comment