Gbajugbaja olorin Fuji K1 the Ultimate, lo se ipade pelu Aare Buhari loni ni Abuja

Ipade waye loni laarin gbajugbaja olorin Fuji kwam 1 ati Aare Buhari ninu ile ijoba to wa ni Aso Rock ni ilu Abuja. K1 lo se afihan aworan na lori ero ayelujara instagram.
O fi idunu re han, o si dupe lowo Olorun fun ore ofe ti ohun ri gba.

Comments