#Plateaukillings; Ajo DSS ti gbe ojise Olorun Isa El Buba fun iforo wani lenu wo



Gbajugbaja Ojise olorun ti ilu Jos Isa El Buba ni iroyin fi to wa leti wipe awon osise ajo DSS ti lo gbe ni ile re. Eyi waye leyin igba ti ojise Olorun na se afihan mohun-maworan kan lori ero ayelujara instagram lati fi enu ete kan ijoba apapo lori ipaniyan ton waye lojojumo ni ipinle Plateau.
Awon ti oro na se oju won so wipe iforowanilenuwo lasan ni won so wipe won fe ba se.

Comments

Post a Comment