Aare Buhari ti setan lati rin irinajo lo si orilede Togo fun ipade ECOWAS, yo si se ipade pelu awon omo orilede Nigeria ton gbe orilede Togo paapa julo awon to wa ni ilu Lome ni olu ilu orilede na.
Ipade ECOWAS na yo da lori bi alafia o se wa ni gbogbo awon omo orilele to wa labe egbe na, bi igbayegbepo alafia o se wa laarin awon orilede na.
Ipade ECOWAS na yo da lori bi alafia o se wa ni gbogbo awon omo orilele to wa labe egbe na, bi igbayegbepo alafia o se wa laarin awon orilede na.
Comments
Post a Comment