Arakunrin, omo egbe oloselu PDP kan so emi re nu ninu ijamba oko kan ni ipinle Kogi +18







Isele ijamba oko kan waye loni ni ilu Omala ni ipinle Kogi nibi ti arakunrin kan, omo egbe oloselu PDP kan ti oruko re nje Haruna ti so emi re nu.
Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won se, won so wipe arakunrin Haruna na lo wa lori okada re, ti oko ayekele kan si lo ya ba nigbati awako na kosi koto kan to wa ni oju opopona na.
Awon eleso abo ilu ti gbe oku ologbe na lo si ite igbokusi kan to wa ni ipinle na.

Comments