Awon agbofinro ti lo fipa mu Aare ile igbimo Asofin Bukola Saraki ati igbakeji re Ike Ekweremadu




DSS, EFCC storm Ekweremadu?s residence in AbujaDSS, EFCC storm Ekweremadu?s residence in Abuja











DSS, EFCC storm Ekweremadu?s residence in Abuja
Iroyin fi to wa leti wipe awon agbofinro ti no dena de Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki ni aro oni ni opopona  Lake Chad Crescent ni agbegbe Maitama district ni ilu Abuja. Gege bi atejade ti ogbeni Bamikole Omisore se lori ero ayelujara twitter, o so wipe awon agbofinro na de lona lati lo ri oga olopa leyin ipe to fi sowo si latari idigunjale to waye ni ilu Offa ni ipinle Kwara.
Bakana, igbakeji Aare ile igbimo asofin na ni awon osise DSS ati EFCC ti lo mu ni ile.

Comments