Awon aworan nibi iwode ita gbangba egbe oloselu APC to waye ni ipinle Kwara






Minisita Alhaji Lai Mohammed loni lo si ilu Oro ni ipinle Kwara lati lo dari iwode ita gbangba ati ipade kan fun egbe ololselu APC ni ipinle na.
Ipade na waye lori bi egbe oloselu na o se te siwaju, ti orire o si se to won lowo ninu idibo ton bo wa ni odun 2019.

Comments