Ogagun Gaius Garba ni iroyin fi to wa leti wipe awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam ti pa ninu ikolu kan to waye laarin won ni ipinle Borno. Iyawo ati omobirin kan lo gbeyin ogagun na.
Awon ore ati molebi re ti se opopolo atejade lori ero ayelujara lati kedun iku akoni na. Adura wa ni wipe ki Olorun fi Orun ke ologbe na. Amin.
Comments
Post a Comment