Awon Senito Mẹdogun ti kuro ninu egbe oloselu APC bo si egbe oloselu PDP

Aare ile igbimo asofin orilede Nigeria Bukola Saraki loni nibi ipade awon omo egbe ti fi han wipe awon Senito Medogun ti pinu lati fi egbe oloselu APC sile, lasi ti darapo pelu egbe oloselu PDP.
Oruko awon Senito na niyi;

Sen Lanre Tejuoso(Ogun)
Sen. Shaaba Lafiagi
Sen. Barnabas Gemade
Sen. Dino Melaye
Sen. Shittu
Sen. Rafiu Ibrahim
Sen. Shitu Ubali
Sen. Isa Misau
Sen. Sulaimon Hunkuyi
Sen. Monsurat Sunmonu
Sen. Mohammed Danbaba
Sen. Bayern Nafada
Sen. Suleiman Nazif
Sen. Rabiu Kwankwaso
Sen. Abdulazeez Murtala-Nyako

Comments