Akojopo awon egbe oloselu PDP ti se atejade kan to fi han wipe awon ti le awon merin kan to fowosopo lati gbogun ti egbe oloselu na ni ipinle Ekiti ni odun 2017. Oruko awon merin yi ni Senito Buruji Kashamu, Semiu Sodipo, Bayo Adebayo ati Segun Seriki.
Comments
Post a Comment