Gbajugbaja odomodekunrin agbaboolu Mesut Ozil ti pinu lati feyinti gege bi agbaboolu fun orilede JAMANI latari iwa eleyameya ati ailakasi ti Aare orilede JAMANI wu si leyin idije ifesewonse agbaye Fifa Worldcup to waye ni orilede Russia.
Ninu atejade to se lori ero ayelujara twitter, o se afihan awon idi ti ohun fi pinu lati fi egbe agbaboolu orilede na sile. O so siwaju si wipe agbaboolu ni oun, oun o ki se oloselu nitorina ko ye ki Aare orilede JAMANI so oro buruku si ohun.

Atejade to se ni yi ni ede geesi;
Comments
Post a Comment