Isele ijamba ina sele ni ile eko giga Adekunle Ajasin ni ilu Akungba Akoko ipinle Ondo. Gege bi oro ti awon ti oro na se oju won so, won fi han wipe ile ifowopamo merin gbako lo fi ara gba ijamba ina na.
Awon osise ile ise panapana lo gbiyanju lati pa ina na.
Comments
Post a Comment