LORI LE, O DI GOBE! Won ti gbe gomina ipinle Ekiti Ayodele Fayose lo si ile iwosan leyin igba to daku ni ilu Ado





Gobe ti sele ni ipinle Ekiti, ninu atejade ti agbenuso fun gomina ipinle Ekiti ogbeni Lere Olayinka se, o fi han wipe won ti gbe Gomina ipinle na Ogbeni Ayodele Fayose ti daku won si ti gbe lo si ile iwosan leyin igba ti awon olopa yin taju-taju sinu ibise Gomina na.

Atejade ti ogbeni Lere Olayinka se ni yi lori Twitter;

Comments

Post a Comment