Nina, ikan ninu awon oludije ninu idije Big Brother Naija ti keko jade ni ile eko giga




Ikan ninu awon oludije ninu idije Big Brother Naija, Nina se afihan awon aworan yi lati fi han wipe ohun ti keko jade ni ile iwe giga to wa ni ipinle Imo.
O dupe lowo Olorun ati awon ololufe re fun ife ati igbiyanju won lati ri wipe ohun se aseyori lenu eko re.

Comments