Senito Ademola Adeleke ni yo je oludije fun egbe oloselu PDP ninu eto idibo fun ipo Gomina ipinle Osun ni osu kesan odun yi. Eyi waye latari wipe Senito na lo gbegba olubori ninu idibo elegbejegbe to waye ninu egbe oloselu na ni ana.
Senito na lo na awon akegbe re bi Dr. Akin Ogunbiyi, Ogbeni Adejare Bello, Ogeni Adeolu Durotoye, Jide Adeniji, Sen. Olasunkanmi Akinlabi, Ogbeni Ayoade Adewopo, Ogbeni Lere Oyewumi ati Ogbeni Felix Ogunwale.

Comments
Post a Comment