Awon omo ologun pa awon daran-daran mokanlelogun ni ipinle Benue

Awon omoologun Nigeria pelu inagije  Operation Whirl Stroke (OPWS) ti pa awon odaran daran-daran mokanlelogun ninu ikolu kan to waye laarin won ni agbegbe Gbajimba-Akor-Tomata ni ijoba ipinle Guma ni ipinle Benue.
Ogagun Major General Adeyemo Yekini fi idi oro na mule nigba ton ba awon akoroyin soro, o si so siwaju si wipe meji ninu awon omo ologun lo so emi won nu.

Comments