Aworan nibi ayeye igbeyawo laarin gbajugbaja olorin Becca ati Tobi Sanni Daniel
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Gbajugbaja odomodebirin olorin Becca, loni se igbeyawo pelu ololufe re ogbeni Tobi Sanni Daniel, Ayeye igbeyawo na lo waye ni orilede Ghana, ti gbogbo awon ololufe won si jade lati ye won si. Ijo, idunu ati ayo ni won fi se ayeye na. Eku ori ire o.
Comments
Post a Comment