Gomina ipinle Oyo Abiola Ajimobi fi erin ati oyaya ki gbajugbaja olorin emi Yinka Ayefele nibi ayeye ojo ibi Olubadan

Leyin gbogbo atotonu ati rogbodiyan to be sile laarin ijoba ipinle Oyo ati Yinka Ayefele ni nkan bi ose kan seyin lori wiwo ile ise arakunrin na. Iyalenu nla lo je fun awon ololufe Yinka Ayefele nigba ti won ri oun ati Gomina ipinle Oyo papo nibi ayeye ojo ibi Olubadan pelu erin lenu won.

Ayeye ojo ibi Olubadan of Ibadan, Oba Saliu Adetunji lo waye ni ilu Ibadan loni, opolopo awon gbajugbaja ati olokiki eniyan lo peju sibi ayeye na.

Comments