Ipade waye laarin Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki ati Aare orilede Nigeria nigbakanri Goodluck Jonathan

Ipade idakonko waye loni laarin Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki ati Aare orilede Nigeria nigbakanri Ebele Jonathan ni ilu Abuja.
Idi ipade yi lo si je Kayefi si gbogbo eniyan, sugbon won mu da awon oniroyin loju wipe lai pe, won o je ki won mo idi ti ipade na fi waye.

Comments