Ipade waye laarin Atiku, Babangida ati Abdulsalam Abubakar ni ipinle Niger





Ipade idakonko waye laarin igbakeji Aare nigbakanri Atiku Abubakar, ajagun feyinti Ibrahim Babangida ati Abdusalam Abubakar in ilu Minna, olu ipinle Niger. Ipade na da lori bi eto idibo odun 2019 o se lor ni irowo rose, ti alafia o si se deba orilede Nigeria.

Idunu ati ayo ni awon adari orilede meta yi fi pade arawon ti won si so asoyepo to dan manran.

Comments