Kayefi nla lo je nigbati olowa ilu odo oro Oba Gbadebo Ogunsakin so emi re nu latari ikolu kan ti arakunrin olode ori kan to wo inu aafin na wa, to si fi obe gun Oba na pa.
Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won so, won ni arakunrin na lo ja wo inu aafin na ni ogunjo osu jeko, to si gun Oba na pelu obe, lai moye igba titi ti Oba na fi ku.
Iwadi fi han wipe omo idile Oba kan na ni Oba na, ati arakunrin olode ori na. Iwadi to peye ti bere lori oro na, won si ti gbe oku Oba na lo si ite igboku si.

Comments
Post a Comment