Oludije fun ipo Aare orilede Nigeria, ogbeni Fela Durotoye ti wole leyin igba ti awon omo egbe PACT (Presidential Aspirants Coming Together) fowo sowopo lati fa kale.
Egbe PACT inu eyi ti awon oludije bi Fela Durotoye, Kingsley Moghalu ati Yele Sowore wa ni won fi idunu won han, won si so fun wipe ko tesiwaju ninu igbiyanju re lati gbe orilede Nigeria de ipile to kan ni awujo awon orilede agbaye.
Ninu atejade ti ogbeni Fela Durotoye se, o dupe lowo awon akegbe re ati gbogbo awon ololufe re, o si se ileri lati je asujo rere fun egbe na.
Atejade to se ni yi ni ede geesi;

Comments
Post a Comment