Ojogbon Kofi Annan ti ku

Ogbontarigi oloselu, ojogbon ati adari UN nigbakanri Kofi Annan ti dagbere fun aye wipe o digba o se ni aaro oni. Iroyin fi to wa leti wipe orilede Switzerland ni baba na ti ku loni leyin aisan ranpe.
Omo  ọgọrin odun ni baba na ki olojo to de.
Adura wa ni wipe ki Olorun te won si afefe ire.

Comments