Ori ko arakunrin kan yo ninu ijamba oko ni ipinle Delta






Iyalenu nla lo je fun awon ara adugbo Effurun ni opopona NPA ni ipinle Delta nigba ti arakunrin kan fi ese ara re rin jade ninu ijamba oko to sele si, eleyi to lagbara de ibi wipe oko re pin si meji.

Arakunrin na eni ti oko re fi ori so igi ope so kale ninu oko na, o si bere sini dupe lowo Olorun Oba.

Comments