Aare Buhari se ipade pelu oga agba ajo DSS tuntun Yusuf Magaji


Aare Buhari loni gba oga agba ajo DSS tuntun Yusuf Magaji ni alejo ni ile ijoba to wa ni ilu Abuja fun ipade ranpe kan.

Idi ipade na wayi lo je kayefi si gbogbo eniyan nitori wipe igba akoko ni yi ti Aare Buahri o pade oga agba ajo DSS na.

Comments