Afinju oloselubirin Funke Adedoyin ti ku

Afinju oloselubirin ati omo egbe ile igbimo asoju ton soju Irepodun Isin/ Ekiti /Oke Ero ni ipinle Kwara, arabirin Funke Adedoyin ti ku. Iwadi fi ye wa wipe arabirin na jade laye leyin to ba aisan jejere jijakadi.

Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin

Comments