Arabirin orekelewa Agbani Darego ti bi omo kunrin lanti-lanti

Arabirin orekelewa Agbani Darego ati oko re ti bi omo kunrin lanti-lanti ni ile iwosan kan to wa ni ilu Oyinbo.

Eku orire o.

Comments