Agbenuso ile igbimo asofin Yakubu Dogara ti kuro ninu egbe oloselu APC bo si egbe oloselu PDP


Agbenuso ile igbimo asofin Ogbeni Yakubu Dogara loni lo se abewo si olu ile ise egbe oloselu PDP lati gba iwe ase lati le dije fun igbakeji ni odun 2019.

O si se afihan wipe oun ti pinu lati kuro ninu egbe oloselu APC bo si egbe oloselu PDP.

Comments