Ajo INEC ti ko lati yan eni to gbe igba oroke ninu eto idibo Gomina ipinle Osun

Ajo Independent National Electoral Commission, INEC, ti ko lati yan enikeni gege bi eni to gbe igba oroko ninu eto idibo Gomina ipinle Osun.

Bo ti le je wipe Oludije labe egbe oloselu PDP Ademola Adeleke lo ni ibo to poju ninu idije na, Ajo INEC fi idi re mule wipe awon kudie kudie kan wa ninu eto idibo na, nitori eyi, won ti sun idibo siwaju ni awon ijoba ipinle kokan.

Atejade oro ti ajo INEC se ni yi ni ede geesi;
 Full Statement: INEC declares Thursday 27th as date for Osun governorship election re-run

Full Statement: INEC declares Thursday 27th as date for Osun governorship election re-run

Comments