Ajo INEC ti yan Oludije labe egbe oloselu APC Gboyega Oyetola gege bi eni to gbe igba oroke ninu eto idibo Gomina ipinle Osun

Oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe egbe oloselu APC ti gbe igba oroko ninu eto idibo to waye ni ipinle na loni.

Leyin gbogbo atotonu ati igbiyanju egbe oloselu PDP lati fakoyo ninu eto idibo elekeji to waye ni ojo ketadinlogbon Osu yi ni egbe oloselu APC ti gba ipo Gomina ipinle na.

Eku orire o.

Comments