Odomodebirin akeko ile iwe giga Ambrose Ali University ti oruko re nje Blessing ni iroyin fi to wa leti wipe o ti so emi re nu ninu ijamba oko kan to waye ni ipinle Edo.
Ololufe arabirin na, eni ti awon ti oro na se oju won so wipe o wa oko na farapa yana-yana, o si wa ni ese kan aye, ese kan orun ni ile iwosan kan to wa ni ipinle Edo.
Comments
Post a Comment