Arabirin Efemena Okedi iyawo ologbe Raskimono ti ku leyin Osu meta ti oko re jade laye

Ibanuje nla lo je nigba ti iroyin iku arabirin Efemena Okedi iyawo ologbe Raskimono to wa leti.

Iku arabirin na waye leyin Osu meta ti oko re jade laye. Atejade ati afihan na waye lati enu arakunrin Soso Soberekon, ninu atejade to se ni ede geesi lori ero ayelujara instagram.

Atejade na ni yi;

'very very Sad News That Late Reaggae Legend Raskimono's wife Efe Okedi Raskimono is also dead at about 3.am today Sunday 23rd September 2018. Rest In Peace my friend and sister'.

Comments