Atejade oruko awon to gba ami eye nibi ayeye FIFA Football Awards 2018

Ayeye FIFA Football Awards 2018 to waye loni ni Royal Festival Hall ni ilu London ni awon agbaboolu to pegede ti gba ami eye lorisirisi.

Awon to gba ami eye nibi ayeye na ni yi ni ede geesi;

Men’s Player: Luka Modric

Women’s Player: Marta

Men’s Coach: Didier Deschamps

Women’s Coach: Reynald Pedros

Goalkeeper: Thibaut Courtois

Puskás Award: Mo Salah

Fan Award: Peru supporters

Fair Play Award: Lennart Thy

World11: David De Gea; Dani Alves, Marcelo, Sergio Ramos, Raphael Varane; Eden Hazard, N’Golo Kante, Luka Modric; Cristiano Ronaldo, Kylian Mbappe, Lionel Messi.

Comments