Awon aworan nibi ayeye igbeyawo laarin oserebirin Lala Akindoju ati arakunrin Oritsegbubemi Fregene

 Ayeye igbeyawo waye laarin oserebirin Lala Akindoju ati arakunrin Oritsegbubemi Fregene loni ni ilu Eko.
Opolopo awon eyan jankan-jankan lo peju sibi ayeye igbeyawo na, ti won si fi idunu ati ayo ba awon toko-taya na se ayeye na.









Comments