Gomina tuntun ni ipinle Osun Gboyega Oyetola, Aregbesola, Akinwunmi Ambode lo se abewo si Asiwaju Bola Tinubu ni ipinle Eko
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Leyin orire to wole to Gomina tuntun ipinle Osun Gboyega Oyetola, oun, Aregbesola, Akinwumi Ambode ati Musilu Obanikoro lo se abewo si agba egbe oloselu APC Asiwaju Bola Hammed Tinubu ni ile re ni Ikoyi.
Comments
Post a Comment