Ijoba apapo labe Minisita fun eto abele Abdulrahman Dambazau ti fi han wipe ojo kini osu kewa ni ayajo odun minira orilede Nigeria.
O fi han wipe ko ni si ise kankan ni ojo na, lati le fun awon omo orilede Nigeria ni anfani lati se ajoyo na pelu awon ololufe ati molebi won lapapo.
Comments
Post a Comment