Odomodekunrin ame'se ku bi ojo Anthony Joshua lu akegbe re Alexander Povetkin ni alubami



Odomodekunrin aja ese Anthony Joshua ninu idije ese kikan to waye loni ni papa idaraya Wembley laarin ohun ati akegbe re Alexander Povetkin omo bibi ilu Russia ni Anthony Joshua ti gbegba oroke nigbato lu ni alubami.

Ija na gbona laarin awon oludije mejeji, ti won si fi ija peta gidi gidi gan. Sugbon owo iya Anthony Joshua dun Alexander Povetkin nigba ti ija na de ipele keje.

Alexander Povetkin gba fun oga re ni ipele keje, Anthony Joshua si gbe igba oroke.

Comments