Ajo apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le eto iyanselodi lati ojo kefa osu kokanla ti ijoba apapo ba ko lati fi owo kun owo osu awon osise ijoba ni orilede yi.
Ninu atejade ti Aare apapo egbe awon osise Ogbeni Ayuba Wabba se, o fi han wipe iwa aibikita ijoba si oro alafia ati igbayegbadun awon osise ijoba ni orilede yi ti koja afarada. Oso siwaju si wipe ti ijoba apapo ba ko lati fi owo kun owo awon osise na, gbogbo eto oro aje orilede yi ni awon o ti pa.
O wa ro gbogbo awon omo orilede Nigeria bakana wipe ki won gbiyanju lati ra ounje sile won, ki eto iyanselodi na ma fi iya ai nidi je awon mekunu.

Comments
Post a Comment