Ile igbimo asofin orilede Ethiopia ti yan arabirin Zewdw Sahle-Work gege bi Aare ile igbimo orilede na leyin igba ti Aare Mulatu Teshome ko iwe fi ise sile.
Ninu atejade ti Aare tuntun na se, o fi han wipe inu ohun dun pupo lati sise fun awon omo orilede Ethiopa, wipe ifowosowopo ati atileyin won ni ohun nilo lati le je ise ti won gbe le ohun lowo.

Comments
Post a Comment